Home / Àṣà Oòduà / Ìpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won yóò dìbò fún eni tí won fé gégé bí gómìnà Omolúàbí.

Ìpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won yóò dìbò fún eni tí won fé gégé bí gómìnà Omolúàbí.

Gégé bí a ti mò wípé òní tí ó jé Ojó Àbáméta ni ìpínlè Osun yóò dìbó fún ènìyàn tí won fé kí ó di aláse lórí won. Egbé kòòkan sì ti fi omo egbé sílè .
Gboyega Oyetola ni ó dúró fún egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC; Ademola Adeleke, ni ó dúró fún egbé tí a mò sí PDP, egbé alábúradà tí Iyiola Omisore sí dúró fún egbé Elésìn tí a mò sí SDP.
Ìpínlè Òsun ó dowó yín ooo, èyin omolúàbí e ronú ó.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo