Home / Àṣà Oòduà / Gómìnà ìpínlè Osun kéde ojó Ajé(Monday) fún oludé fún ìsèsi tí yóò wáyé ní 20/08/2018.

Gómìnà ìpínlè Osun kéde ojó Ajé(Monday) fún oludé fún ìsèsi tí yóò wáyé ní 20/08/2018.

Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Aregbesola ti kéde oludé fún gbogbo òsìsé ìjoba fún odún ìsèsí tí yóò wáyé ní òla ogúnjó osù kejo odún 2018.Asèyí se àmódún, ìsèsi á gbè wá oooo.

Ìsèsi á gbè wá o.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo