Jackie Appiah dàbí egbin nínú aso ìbílè tí ó wò.

   Òsèré orílè èdè Ghana, Jackie Appiah, èyí rewà ju kí èèyàn fi ojú paáré lo, òsèré yí ló pin sí orí èro ayélujára láti pín àwòrán tí ó rewà yí níbi tíó ti wo aso ìbílè tí a mò sí Ankara.[starlist][/starlist]

Comments

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *