Home / Àṣà Oòduà / Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.

Jude Okoye tí ó jé ègbón àwon psquare ti rò wípé àsìkò ti tó kí òun sòrò lórí Aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè.

Ó ti dá àwon olólùfé won lóhùn lórí èro ayélujára (Instagram), Jude Okoye ti fi ogbón sòrò nípa aáwò tí ó wà láàrin àwon àbúrò rè tí ó sí wípé òun kó ni olórí ebí won.
Ó ko síbè wípé.
“A le fi tipátipá mú Esin lo sí odò sùgbón a kò le fi tipátipá fun lómi mú”.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?