Home / Àṣà Oòduà / Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .

Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .

Juliet Ibrahim ti fé Iceberg Slim won sì ti se ìgbéyàwó ní kóòtù .
Afòròdárà (rapper) tí ó n jé Iceberg Slim àti òsèré bìnrin Juliet Ibrahim ti so ìfé won pò pèlú ìfenukonu léyìn tí won ti se ìgbéyàwó ní kóòtù tán.
Èyí ye wón gan ni a kí yín kú oríre.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo