Home / Àṣà Oòduà / Murphy Afolabi se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún kerin lé l’ógójì ní Toronto, Canada.

Murphy Afolabi se ayeye ojó ìbí rè nígbà tí ó pé odún kerin lé l’ógójì ní Toronto, Canada.

Òsèré orí ìtàgé, Murphy Afolabi se ayeye ojó ìbí rè ní ojó mélòó séyìn.
Òré àti ojúlùmò tí won jé èníyàn pàtàkí, gbajúgbajà Òsèré, adarí eré abbl ti se ayeye ìjònilójú fún omo bíbí ìpínlè Osun tí a bí ní odún 1974.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?