Home / Àṣà Oòduà / Òdóbìnrin orílè-èdè Nàíjíríà kan se ayeye ojó ìbí rè tí ó sì há oúnje fún àwon aláìní.

Òdóbìnrin orílè-èdè Nàíjíríà kan se ayeye ojó ìbí rè tí ó sì há oúnje fún àwon aláìní.

    Òdómobìnrin orílè-èdè Nàíjíríà ni ó pinnu láti se ayeye ojó ìbí ní àrà òtò, nígbà tí a ri tí ó n pín oúnje àti àwon nkan míràn fún àwon aláìní, omodé àti àwon èèyàn míràn . ònà ni a ti pàdé rè ní Owerri ní ìjoba ìpínlè Imo .

Òpòlopò àwon èèyàn ni ó yìn….

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?