Home / Àṣà Oòduà / Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .

Omoge kan ni owó tè tí won sì fi se èsín látárí wípé ó fo odi ilé onílé láti jí bisikitì .

       Ònlò èro ayélujárá ( Facebook) tí a mò sí Arc Pashal Chike Umeobi ló so wípé arábìnrin yí ni owó àwon figilanté tè ní Ezinifite , ìlú kan ní ìpínlè Anambra .

Arábìnrin yí ni won fi èsùn kàn wípé ó fo odi ilé láti jí ìpápánu tí a mò sí bisikitì ni owó pálábá rè bá ségi nígbà tí ìkan lára àwon figilanté ri wípé ògbòn n rùn, figilanté náà bá gbìyànjú àti mu sùgbón tí ó bó, ó sì yìn ìbon lùú tí ó sì yè é n ló bá tún fo odi ilé míràn láti balè nínú ilé onílé míràn ,kíá ni onílé yára figbe bonu, béè ni owó bá tè é….

About Awo

One comment

  1. Haha……. O mu bisikiti, Haa……Ebi n pa niyen, Se ko jin pure water ni. (Olee……….)

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?