Home / Àṣà Oòduà / Ooni ti ile-ife ní ìdí òpe àgùnká .

Ooni ti ile-ife ní ìdí òpe àgùnká .

Ayeye Odún ifá àgbáyé eléyìí tí ó wáyé ní òkè-ìtase ní ilú ilé-ifè.   Ooni rèé ní ìdí òpe àgùnká ní ibi tí mùtúmùwà ti ń se àdúrà sí ìsèdá won, kódà oba náà kò jáfara.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo