Home / Àṣà Oòduà / Reekado banks wà pèlú àwon òdóbìnrin tí won yááyì “ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà lójojúmò.

Reekado banks wà pèlú àwon òdóbìnrin tí won yááyì “ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà lójojúmò.

Ìkan lára àwon omo olórin abé ikò Marvin, Reekado banks pín àwòrán sí orí èro ayélujára tí a mò sí instagram, èyí tí ó yà pèlú àwon òdóbìnrin tí won férè wà ní ìhòhò. Tí ó sì ko síbè pé Ka bíbélì re kí o sì gbàdúrà ní ojojúmó.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?