Category: Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

  • Maheeda di Pasito oloro itunnu

    Kosi eni ti Olorun ko le fi owo to lokan. Maheeda, okan ninu awon olorin ile Naijiria, ti ma n bora sile nihoho tele ti wa di eni ti n gba awon eniyan niyanju bayii pelu oro itunnu ti n mu inu awon ololufe re dun.

  • Dayo Amusa ti pada senu ise

    Dayo Amusa wa lara awon ero Mecca odun yii pelu awon akegbe re bi Fathia Balogun ni won jo goke arafa papo. Igba ti won de ni won di Alaaja tuntun. Sugbon bayii, Dayo ti pade sidi ise oojo re nibi won ti n dana fiimu tuntun.

  • Eleleture lati owo Akeem Lasisi

     

    Eyi ni fidio orin ewi lati owo Akeem Lasisi ti won pe akole re ni ELELETURE

  • Somi Edumare lati owo Edaoto

    Odun lo sopin, eni Edua Oke pamo nikan lo yege. Sugbon nipa temi ati awon ololufe mi, a ko ni padanu enikeni lase Eledumare. Ase
     Lori eyi ni i ti ma fi yin sile lati je igbadun orin Edaoto to pe ni Somi Edumare.

  • Ika eniyan wo lo yo oju Ibrahim sa lo?

    Okunrin olokada kan ti won pe oruko re ni Ibrahim ni won sadeede ba oku re loju titi laaaro yii ni agbegbe Alaba Suru to wa loju ona masose Badagry niluu Eko. Igba ti won yoo ye okunrin naa wo, won ri wi pe won ti yo oju re sa lo.

  • London, e ku amojuba Omo Baba Olowo

    Davido ti se afihan foto re lenu irin ajo re silu London. Ninu atejade yii ni Omo Baba Olowo ti n so wi pe oun ti n sun mo ilu London.

    Eyin ara London, se e ti wa ni imurasi?

  • Ojo ibi Fayose: E wo ohun ti awon tisa fi da lola

    ojo_ibi

    Gomina Ayodele Fayose se ayeye ojo ibi odun marunlelaadota (55) lonii ni Ipinle Ekiti. Akara oyinbo yii ni awon tisa fi da lola.

  • Ohun te e ma se ti e ba fe ki irun yin gun daada


    Fun awon omoge iwoyii ti won fe nirun gigun, ti yoo dudu kirimi ti yoo si ma dan bi koroshin, ti irun naa kosi ni maa ja butebute bi owu, ogun re niyii to daju bi ada. E wa ewe eti erin ti a mo si aloe vera ati igbo mimu tutu (india hemp), awon nnkan mejeeji yii ni e o lo papo. Ti e ba ti se eleyii tan, e da sinu iparun ti e n lo. E maa fi pa irun yin lojoojumo.

    Irun yin yoo dudu, yoo tun ridi mule, irun naa yoo si fe e gun de ibadi yin.

  • Akoni osere onitiata: Bimbo Thomas gbayi!

    Orisiirisii eniyan lo wa laye pelu agbara inu eleyii ti Oba oke da mo onikaluku won. Eyi ti Oluwa fun Bimbo Thomas lo je eyi to jo mi loju ju. Yato si wi pe Edua oke fun lebun ise tiata sise, omobirin naa je eni to maa n dunnu nigba gbogbo. Kii gba ohunkohun laaye lati ba idunnu re je, yala nipa awon oro ti ko fidi mule ti awon eniyan maa n so nipa awon elere ori itage.
    Bimbo je enikan to n maa fi ero okan re han lai beru ohun ti enikeni le so nipa re.

    Bimbo rewa lobirin, o si je enikan to nife awon eniyan re gidigidi. O feran oge sise, o si tun so wi pe ife oun si oti waini lo mu oun da ile itaja ti won ti n ta oti waini sile. Bimbo Thomas ni akoni mi fun osu yii. To ba tun ya, maa ma so die sii nipa oba oge, eleyinju ege, onibadi aran, alase ati oludari BIMBALLY Wine & Liquor.

    Sugbon sa, ki n to dake, kilode ti sisi naa laiki fesikaapu pupo na?