Home / Àṣà Oòduà / Ohun te e ma se ti e ba fe ki irun yin gun daada

Ohun te e ma se ti e ba fe ki irun yin gun daada


Fun awon omoge iwoyii ti won fe nirun gigun, ti yoo dudu kirimi ti yoo si ma dan bi koroshin, ti irun naa kosi ni maa ja butebute bi owu, ogun re niyii to daju bi ada. E wa ewe eti erin ti a mo si aloe vera ati igbo mimu tutu (india hemp), awon nnkan mejeeji yii ni e o lo papo. Ti e ba ti se eleyii tan, e da sinu iparun ti e n lo. E maa fi pa irun yin lojoojumo.

Irun yin yoo dudu, yoo tun ridi mule, irun naa yoo si fe e gun de ibadi yin.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...