Home / Àṣà Oòduà (page 146)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Aye ye Rotimi Amaechi ninu Abuja

Aimoye ero wa pade Rotimi Ameachi nikete to jade ninu ile igbimo asofin Abuja lonii.   Foto Rotimi Amaechi ati iyawo re leyin to yege niwaju ile igbimo asofin agba gege bi minisita ti won yan

Read More »

E wa wo bobo to fi tattoo ya Davido si aya re

Davido pada pade bobo to fi tattoo ya aworan omo baba olowo si igbaaya re. Ebun ti Davido fun naa ni alakorun ti won fi goolu se. O si so fun bobo naa wi pe awon ti di abi kan ...

Read More »

[Foto] Aso oge Toyin Aimakhu le ku! #Igo loju omo odaran

#ToyinAimakhu Se igo yii o wa poju?

Read More »

Kukute ti darapo mo awon alakatakiti esin Islam

Okunrin arara yii ni won ti ri pelu awon alakatakiti esin Islam, Jabhat Al-Nusra niluu Syria. Jabhat Al-Nusra yii ni o ni ajosepo pelu iko AlQaeda eleyii ti Osama Bin Laden wa lara awon oludasile re ko to di wi ...

Read More »

Ki lo sele si Taiwo leyin iku Kehinde Osuolale (Ibeji Oran)?

Leyin odun kan ti Kehinde Osuolale dagbere faye, iroyin mi-in tun ti kan wa wi pe ikeji re, Taiwo naa ti lo ba ikeji re lajule orun. Ohun ti a gbo ni wi pe ilu Abuja ni Taiwo ku si. ...

Read More »

Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe

Ninu Iroyin Owuro ose yii: Okunrin kan ko N2M owo ifeyinti re fun pasito ni Mowe, loro ba di gobe Iroyin Owuro ose yii tun ti gori igba. Iwe iroyin ti n gbona felifeli. Die ni yii ninu awon koko ...

Read More »

Ogulutu: Olaju ti so ogbon aye atijo di omugo patapata

#Ogulutu Nigba ti mo wa ni kekere, awon egbon adugbo kan wa, awon ti awon obi wa gba wi pe won nimo ju wa lo. Ti o ba ti n to akoko fun awon egbon ti wa lati wo ile ...

Read More »

Ayeye Ojo Ibi Oba Lamidi

Oba Alhamis Olayiwola Atanda Adeyemi, Alaafin ti ilu Oyo, pe eni odun metadinlogorin (77) lojo keedogun osu kewaa odun yii loke eepe. Ayeye ojo ibi Oba Lamidi ni Omooba Akeem Adeyemi, eni to je okan lara awon omo ile gbimo ...

Read More »

E wo ohun ti bobo yii se fun afesona re nita gbangba

Laaarin ile itaja nla kan niluu Warri, bobo yii kunle fun ololufe re. O mu oruka ife jade lapo, o si wi bayii wi pe: “Joo ololufe mi, nje o gba lati je iyawo mi?” Opolopo awon eniyan ti won ...

Read More »

Awon eniyan ti bere si ni fi adura ranse si oga @DeleMomodu

@DeleMomodu, okan ninu awon oga oniroyin ile Naijeria, eni ti pupo ninu awon akegbe re feran lati maa pe ni Bob Dee, ni okan ninu oju meji re n yo lenu bayii. Won ti se ise abe fun adari ati ...

Read More »