Home / Àṣà Oòduà (page 147)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Gbenga Ojoyido n jaye bi oba Lamidi niluu Amerika

Won ti so mi lenu, idi ni yii ti mo fi pinnu lati dake. Won ti fabuku kan mi, idi ni yii ti mo fi senu mi ni deede sibi. Awon kan tile leri wi pe maa kandin ninu iyo, ...

Read More »

Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun

Orisun Ile Igbimo Asofin ipinle Kwara ti kede ojo ayewo awon komisanna tuntun Olayemi Olatilewa Ile igbimo asofin Ipinle Kwara ti kede ogunjo osu kewaa odun yii [20/10/15]gege bi ojo ti won yoo se agbeyewo awon komisanna tuntun ti gomina ...

Read More »

Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin.

Orisun Awon olokada rogo lowo olopaa ilu Ibadan: Won ni ese nla ni lati gbero meji seyin. Olayemi Olatilewa Awon olopaa ilu Ibadan ti bere si ni mu awon olokada ti won ba ti ko ju ero kan lo seyin ...

Read More »

Awon olopaa gba owo inu saka nla mesan-an pada lowo awon adigunjale banki.

Orisun   Awon olopaa fako yo! Won gba owo inu saka nla mesan-an pada lowo awon adigunjale banki. Olayemi Olatilewa Awon olopaa digboluja ti won gbogun ti iwa odaran gba obitibiti owo naira pada lowo awon adigunjale ti won dena ...

Read More »

Aye akamara: Abiyamo gbe omo re ta nitori owo

Owo awon osise alaabo ti won dabo bo dukia ijoba, Nigerian Security and Civil Defense Corps, NSCDC, e ka ti ipinle Enugun ti te arabirin kan to fe ta omo bibi inu re ni egberun lona ogorun owo naira Naijiria. ...

Read More »

Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode

Orisun Awon olopaa ti lo ko awon omo egbe okunkun n’Ijebu-Ode *Komisanna lo pase fun awon olopaa Olayemi Olatilewa Owo awon olopaa ipinle Ogun ti te awon afura si kan gege bi omo egbe okunkun ni Ijebu-Ode. Gege bi atejade ...

Read More »

Omo yibo yari mo awon omo ile igbimo asofin Eko lowo.

Omo yibo yari mo awon omo ile igbimo asofin Eko lowo. *O ni oun o fara mo siso ede Yoruba nile igbimo asofin Onarebu Jude Idimogu, okan lara awon omo ile igbimo asofin ipinle Eko, ti tako aba ile lati ...

Read More »

Igba wo ni Pasuma fe ni Aya leyin odun mokandilaadota (49)?

Igba wo ni Pasuma fe n’iyawo leyin odun mokandilaadota (49)? Olayemi Olatilewa Wasiu Alabi Pasuma tun ti pada so fun awon ololufe re wi pe ko ti to asiko fun oun lati ni iyawo nile. Oga Nla fuji, eni ti ...

Read More »

Fayose kede nomba ero ibanisoro re fun awon eniyan ipinle Ekiti

Gomina Ayo fayose ti kede nomba ero ibanisoro re lori eto olosoosu kan to maa waye lori redio ati telifisan ipinle Ekiti, “E PADE GOMINA”. Lori eto yii ni gomina ti n jiyin awon ise iriju re fun awon eniyan ...

Read More »

Se eru nla FIFA ko ni wo Issa Hayatou lorun?

Bi o tile je wi pe iriri odun metadinlogbon (27) ni Ogbeni Issa Hayatou ti ni nipa didari ajo to n ri si ere boolu ile Afirika, Confederation of Africa Football. Sibesibe awon ololufe ere boolu ni awon ilu okeere ...

Read More »