Home / Àṣà Oòduà (page 148)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re

Niluu Abeokuta, apata wo pa iya ati awon omo re. Olayemi Olatilewa Apata kan ti n be loke tente ni agbegbe Iberekodo niluu Abeokuta ti ye lule to si seku pa iya ati awon omo re. Bi eniyan ba je ...

Read More »

ILERA LORO: Bi a se le se itoju ehin enu wa

#Oniroyin @OlayemiOniroyin Aridaju iwadii ti fi ye wa wi pe osan orombo dara pupo ni mimu eleyii to n fun erigi ehin wa ni agbara. Mimu osan orombo ran erigi lowo lati le mu ehin enu wa duro daada nipase ...

Read More »

Igba otun de ba Majek Fashek: O korin ni Felabration

Bi Eledumare  ba ran eda lowo, bi idan ni i ri. Majek Fashek ti opolopo sebi o ti tan fun latari bi okunrin naa se fi ogun oloro baye ara re je, ti ko si ni kobo lowo mo lati fi ...

Read More »

Salawa Abeni korin pelu omo re, BIG SHEFF

BIG SHEFF ni yii, omo SALAWA ABENI. Sheriff Ilori je okan lara omo ti Queen Salawa Abeni bi fun Oba Fuji Alatika, Alhaji Rasaki Kolawole Ilori, eni ti gbogbo eniyan mo si Gen. Kollington Ayinla. Big Sheff je olorin Hip ...

Read More »

Obirin to bi ibeta ni yii leyin ti Boko Haram gba ile lowo won

Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. @OlayemiOniroyin

Read More »

Ijamba oko waye ni Victoria Island lonii

Ijamba oko to waye lonii ni agbegbe. Ozumba Mbadiwe, VI, niluu Eko. Oko ajagbe akeru naa run mo awon oko bi merin kan nigba ti bireki re ko muu mo. Enikeni ko fara pa, dukia lasan lo sofo.

Read More »

Obalufe, igbakeji Oba Okunade Sijuwade ti dagbere faye lonii

Obalufe ti Iremo-Ife, Oba Samuel Omisakin, eni to kangun si Ooni Ile-Ife, Oba Okunade Sijuwade gege bi igbakeji, to tun je olori awon afobaje ti ilu Ile-Ife naa ti dagbere faye lonii [15-10-15].

Read More »

Oserebirin onitiata wo ni yii?

#Oniroyin  Olayemioniroyin.com Taani obirin to wa ninu foto yii?

Read More »

Ore idunnu wole fun awon ti Boko Haram pa lekun nipinle Borno

Arabirin yii bi ibeta (omo meta) ni ipago ti won pese fun awon eniyan ti Boko Haram so di alainile lori to wa ni Bama ni ipinle Borno. E wo linki isale yii: @OlayemiOniroyin  

Read More »

Owo awon olopaa te ole ajipata ati komu niluu Ibadan

Ero o gbese ni olu ile ise awon olopaa ipinle Oyo to wa ni Eleyele nigba ti won se afihan awon igara olosa ajipata ati komu gbe fun awon oniroyin niluu Ibadan. Awon ole bi merin yii lagbo wi pe ...

Read More »