Category: Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

  • Reekado Banks gba Larry Ekundayo l’álejò ní ilé rè.

    Omo ikò ti egbé olórin ìgbàlódé tí a mò sí Mavin, Reekado Banks ti gba okùnrin a gba àmì èye ní àlejò ní ilé rè, àwon méjèjì pín fídíò náà sí orí èro ayélujára.

    E wo àwòrán won ní ìsàlè.

  • Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.

    Arákùnrin kan ni ó fi ìtò ara rè wè látàrí àpòjù ìmukúmu.
    Arákùnrin kan ni a rí ní Ayobo, agbègbè kan ní ìpínlè Èkó tí ó n fi ìtò ara rè wè tí ó rò wípé omi ni látàrí ìmukúmu tí ó ti mu.
    Won ti kìlò títí e kò gbó, ojó wo gan ni e to fékun ìmúkúmu tí kò se ara lóore. P

  • Ayé Kareem ti yí padà di òtun láti ìgbà tí ó ti ya àwòrán Ààre Macron- Alákoso rè ló so béè.

    Óríre míràn ti to omo kékeré, omo odún mókànlá tí a mò sí Kareem Waris Olamilekan tí olórun fún ní èbùn kí ó ma ta nkan, ó ti ya ààre ilè Faransé tí a mò sí Ààre Emmanuel Macron, nígbà tí ó lo se àbèwò sí ojúbo Afrika tuntun ní ìlú Èkó.

    Léyìn tí ó gba ilé ní owó Gómìnà ìpínlè Eko, ilé-ìfowópamó tí a mò sí Eko bank, ti towó bo ìwé láti gbà á tó lówó àwon òbí rè. Lára àwon èjé won ni wípé àwon yòó tó omo náà àti wípé àwon yóò ran lo sí ilé-èkó fún ogún odún(20 years).
    Nínú ìfòrò wáni lénu wò tí won se fún alákoso Kareem tí a mò sí Adeniyi Adewole, ó jé kí ó di mímò wípé gbogbo ònà ni àwon n wá láti dábò bo ojó òla ayàwòrán omodé náà .
    Ó so wípé inú òun dún púpò nítorí ilé-ìfówópamó ti Eco bank látàrí èjé tí won jé láti tójú omo náà. Ó so síwájú wípé sojú òun ni won se nígbá tí ó jé wípé òun ni Alákoso omo náà àti wípé won kò le se léyìn òun.

  • Ìròyìn Òrofó ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

    1 Ààrẹ Buhari yóò dé lónìí láti orílẹ̀ èdè China.

    2 Ọ̀jọ̀gbọ́n Ọ̀ṣínbàjò gba àlejò àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí wọn gbé igbá orókè nínú ìdíje ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé.

    3 Àwọn oníròyìn ń fi ìròyìn burúkú bá ìjọba Buhari jẹ́ – Alákòóso

    4 Àwọn olùdíje ipò àarẹ nínú ẹgbẹ́ PDP yóò yọnu si ẹni ti o ba gbégbá orókè.

    5 Mo ní ọgbọ́n ìṣèlú ju Buhari lọ – Turaki

    6 Ìdìbò Ọ̀ṣun : Falae sọ ìdí tí àwọn olùdìbò ṣe gbọ́dọ̀ dìbò fún ẹgbẹ́ SDP yàtọ̀ di ẹgbẹ́ APC.

    7 Oshiomole bẹnu àtẹ́ lu bí àwọn ọlọ́páà ṣe lọ tú ilé alàgbà Clark.

    8 Ilé iṣẹ́ ọlọ́páà yọ àwọn ọlọ́páà tí wọn tú ilé alàgbà Edwin Clark.

    9 Ilé iṣẹ́ ọlọ́páà gbé àwọn ẹni afurasí méjì-dín-lógún tí wọn dáná sun ilé iṣẹ́ ọlọ́páà ni ìlú Iwo lọ sí ilé ẹjọ́.

    10 Ẹgbẹ́ APC ni Ìpínlẹ̀ Imo yóò lo ètò Ìdìbò gbangba-làṣá-ń-ta láti yan olùdíje gómìnà.

    11 Àwọn olùdìbò mílíọ̀nù ó lè ní kò ì tíì wá gba káàdì Ìdìbò alálòpẹ́ ni Ìpínlẹ̀ Èkó – INEC.

    12 Ẹgbẹ́ Ọdọ APC rọ àwọn ìgbìmọ́ kí wọn dín owó ìdíje kù.

    13 Èrò bílíọ̀nù mẹ́rin ó lé ní bàálù gbé ní ọdún 2017 – IATA

    14 Orílẹ̀ èdè India fọwọ́ sì kí ọkùnrin fẹ́ ọkùnrin gẹ́gẹ́ bí aya.

    15 Orílẹ̀ èdè China yóò dá okoòwò tí ó lé ní tírílíọ̀nù méjì Náírà sí ilẹ̀ adúláwọ̀.

    Ayé wa kò ní dàrú lágbára ELÉDÙMARÈ.. Àmín.

  • Arábìnrin kan ni ó bí ìbeta léyìn odún métàdínlógún tí ó tí se ìgbéyàwó.

    Arábìnrin kan ni ó gbe lo sí orí èro ayélujára tí a mo sí facebook láti lo pín ìròyìn ayò wípé òhun bí ìbeta láti bí odún métàdínlógún sèyìn. Ó ko síbè wípé…
    ” èyin abiyamo mi ò le mú ayo náà móra rárá, ègbón mi bí ìbeta ní àná léyìn odún métàdínlógún tí ó ri se ìgbéyàwó. E jòwó e bámi pín ìròyìn ayò yí.

  • Àwon omo egbé APC ti Gúúsù Oyo ti jóòkó ìgbìmò – Abiola Ajimobi lo kí Alaafin Oyo.

    Gómìnà ìpínlè Oyo , Abiola Ajimobi , tí ó ti fi okàn àwon omo egbé APC ti ìpínlè Oyo lókàn balè wípé omo egbé àwon ló ma wolé ní ibi ìdìbò tí ó n bò lónà ní odún 2019, àti wípé àwon ìlú ló ma dìbò fún won.
    Gómìnà náà ní ti lo kí Alaafin ti Oyo Oba (Dr.) Lamidi Adeyemi keta, ní Oyo fún ìjókòò àwon ìgbìmò asòfin egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC.

  • Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.

    Owó àwon àgbófinró ti te olùsó tí ó fi ipá bá omobìnrin rè òdún méje sún.
    Olùsó Daniel Udoh, tí ó dá ilé ìjosìn “Agbejórò ni jésù” sílè ni owó sìkún ìjoba ti tè ní Akapabuyo, ìpínlè Cross river látàrí fífi tipátipá bá omo rè obìnrin odú méje lòpò.
    Udoh ni won ti fi sèsín káàkiri pèlú àwon mókàndínlógórin(79) elésè míràn ní Calabar.
    Omo rè wà ní ilé-ìwòsàn tí ó n gba ìtójú lówó fún ìjàmbá tí ó selè si.

  • Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

    Gómìnà Aregbesola gun orí okò láti polongo egbé won tí a mò sí APC.

    Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Ogbeni Rauf Aregbesola ti gun orí ténté okò láti polongo egbé won, egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC fún ìdìbó ti odún 2018 ní ìpínlè Osun, ìpínlè omolúàbí.

  • Akékòó bìnrin méjì ja ìjàgbara látàrí òrékùnrin ní ilé-èkó gíga ifáfitì tí a mò sí Tai solarin University of Education, ní ìpínlè Ogun.

    Fídíò àti àwòrán àwon òdóbìnrin méjì tí ó ñ jà látàrí òrékúnrin kan ni ó ti gbalè kan .
    Akékòó ni àwon arábìnrin méjì yí àti wípé akékòó ilé-èkó ifáfitì ti Tai Solarin University Of Education ni won, ìpínlè Ogun, won fi èsùn kàn wípé ìjà won dá lórí arákùnrin tí ó ñ se yáhoo yahoo tí àwon méjèjì jo ñ fé.

    Gégé bí ìtàn se so, ní ilé ìgbé àwon Akékòó tí a mò sí Hostel ni èyí ti selè, ní ibi tí kò jìnà sí mósálásì Ijele.

  • Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.

    Gbajúgbajà olórin ìgbàlódé ti a mò sí Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè rè.  Davido tí ó jé omo ogbó-n-tarìgì àti èèyàn ñlá, tí ó sì jé omo tí ó ti ìdílé olórò wà súgbón tí kò torí owó, orò bàbá rè má sisé mó, tí ó je wípé takuntakun ni ó fí n sisé láti le di èèyàn ñlá àti èèyàn pàtàkì tí àlá rè sì ti wá sí ìmúse. Omo bàbá olówó ni gbogbo ayé mo Davido sí nítori omo ìdílé Adeleke láti Ede ni. Davido ti darapò mó àwon àgùnbánirò láti sin orílè èdè Nìjíríà báyìí.  Sé owo ló tún fé ni àbí kíni? sùgbón ìfé orílè èdè rè tí ó wà lókàn rè ní ó mu fé sin orílè èdè rè.

    davido