Category: Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

  • Omokùnrin odún métàlá (13) ni àwon olópàá ti mú látàrí ìbèrú tí ó ní sí won.

    Omokúnrin kékeré kan ní won ti mó’ lé ní àgó olópàá látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá.
    Gégé bí ìròyìn se so, omokùnrin odún métàlá, tí ó sí jé olórí okúnrin ilé-èkó won, ni ó n pon omi lówó nínú kànga ní iwájú ilé won, nígbà tí ó rí àwon oní jàgídíjàgan ní Itafaji, ní ìpínlè Eko .
    Bàkan náà, látàrí ìbèrù tí ó ní fún àwon olópàá ló mu féré ge nígbà tí ó rí won, èyí sìni èsè rè tí won fi mu láti tì mólé.
    Gégé bí won se so, won ní ó wà lára àwon oní jàgídí jàgan tí ó sá lo, gbogbo wàhálà àwon ará àdúgbò ló sì jásí asán láti jékí won fi sílè, báyìí ni won se mú omo yí àti ìyá rè lo.

     

  • Tiwa Savage kúnlè kí ògá Shínà peter

    Obìnrin àkókó ní inú egbé Marvin kúnlè wò ní orí ìkúnlè nígbà tí ó kí ògà gun àti ògbóntàgirigì tí a mò sí Shina Peter nígbà tí won n sí ilé-isé pefume brand, Sappire Scent ní Lenox mall ní ìpínlè Eko.
    Bákan náà, won tún sí ojú olú polówó ojà won tí a mò sí Cee-C.

     

  • Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.

    Bukola Saraki lo kí Ademola Adeleke ní ìpínlè Osun ní àná.
    Ààre ilé ìgbìmò Asòfin tí a mò sí Dókítà Abubakar Bukola Saraki ní àná tí lo kí omo egbé oní àbùradà tí a mò sí egbé PDP, èyí tí egbé yàn láti lo fún Gómìnà ìpínlè won ní Osun, Seneto Ademola Adeleke tí ìlú ede ní ìpínlè Osun.

  • Àwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn.

    Gégé se gégé, onígègè tó pàdé asòpá ni òr olópàá àti olùwòsàn yí jé, bí olópàá bá kojú dogun tí ó sì pa lára, olùwòsàn tí ó jé ìyàwó rè yóò sì ba wò ó sàn .
    Àwòrán ti aya tí ó n bò lónà àti oko rè, tí ìyàwó jé olùwòsàn tí oko sì jé olópàá yí mà rewà púpò jú o.

  • Ọmùtí Gbàgbé Ìṣẹ́ (Ìrònú Ọlọtí)

    Ilé ọlọ́ti ni ilé ìtura, ibẹ̀ ni àwọn ọ̀rẹ́ ti npàdé fàájì
    Ibẹ̀ náà ni àwọn èké, àti ọ̀dàlẹ̀ tin pàdé ara wọn
    Ti ọti bá wọra tán, ara a sì rọ̀ wọ́n pẹ̀sẹ̀,
    Ìgbéraga á wá wọ̀ wọ́n lẹ́wù
    ọ̀rọ̀ á wá di dánmi wò, ngó ṣe bí mo ṣe tó
    Bi mí́ léèrè nsèké, ó wá di mo sọọ́ tán, àsírí tú
    Ìjà ọ̀dàlẹ̀ kò sì tán bọ̀rọ̀,
    ngó gbẹ̀san, ọ̀dàlẹ̀ di méjì
    Tani kí a báwí? ṣé ọtí ni?
    Tàbí ọlọ́bọ̀bọ̀tiribọ̀?

     

    omuti

    Adeboye Adegbenro

  • Ìpínlè Osun, Ìpínlè Omolúàbí yóò yan ìpín won lónìí, ojó Àbáméta nígbà tí won yóò dìbò fún eni tí won fé gégé bí gómìnà Omolúàbí.

    Gégé bí a ti mò wípé òní tí ó jé Ojó Àbáméta ni ìpínlè Osun yóò dìbó fún ènìyàn tí won fé kí ó di aláse lórí won. Egbé kòòkan sì ti fi omo egbé sílè .
    Gboyega Oyetola ni ó dúró fún egbé oní ìgbálè tí a mò sí APC; Ademola Adeleke, ni ó dúró fún egbé tí a mò sí PDP, egbé alábúradà tí Iyiola Omisore sí dúró fún egbé Elésìn tí a mò sí SDP.
    Ìpínlè Òsun ó dowó yín ooo, èyin omolúàbí e ronú ó.

  • Gómìnà Arégbésolá fún àwon olùkó ní èbùn okò àti àwon èbùn míràn.

    Gómìnà ìpínlè Osun tí a mò sí Rauf Aregbesola lo sí àjo àwon ilé-èkó àwon alákóbèrè pèlú àwon adarí míràn tí won péjú sìbè láti pín okò fún àwon òsìsé.
    Kìí se okò níkan ni ó fún won o bí kò se wípé ó tún fún won àwon èbún míràn.

  • Àwon arákúnrin méjì kan jà lórí eni tí yóò jókòó sí iwájú okò.

    Àwon èrò méjì ni a rí lónìí tí won n jà látàrí eni tí yóò jóko sí iwájú oko ní Èkó . Nígbà tí ó yá ni awakò ti awon méjèèjì jábó látàrí bí won se n se bí eni tí kò ní opolo.
    Kò kúkú sí ohun tí a kò ní rí tán, kárí kâ fojú fò lópò, àfi kí olórun gbà wá.

  • Arákùnrin kan ni ó kú sínú odò nígbà tí ó sòrò nípa èmí òkúnkún.

    Arákùnrin tí ó n gbé ní Èkó ni ó kú nígbà tí ó lo kí ègbón rè ní Ujeme, Ekpoma, ìpínlè Edo, ní won ti rí òkú rè nínú odò ní ilé rè, léyìn tí a gbó wípé ó sonù.
    Gégé bí ìròyìn se so, ègbón olóògbé so wípé ó ún so nípa èmí òkúnkún kí ó tó di wípé won kò ri mó, láti bí ojó mélòó kan sá. Ara rè ni won rí nínú omi tí ó léfòó, ní òwúrò yí.

  • Linda Ikeji padà so orúko baba omo rè, ó wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun àti oko tí n bò lónà.

    Elétí Ofe, Linda Ikeji ti padà so baba omo rè, ó sì ti so wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun .

    Ó tún so wípé orúko omo òun ni Jayce Jeremi , ó ko síbè wípé…
    ” mò n re’lé pèlú omo oba mi. Ìbèrè odún rere nínú ayé mi! Orúko rè a máa jé Jayce, Jayce Jeremi si ni yó ma jé.
    N wó pín àwòrán láìpé”