Category: Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

  • Àwòrán Obanikoro àti Oluremi Tinubu àti àwon omo egbé APC tó kùn ní ìlú èkó.

    Ní ìsàlè yìí ni àwòrán sineto Obanikoro àti sineto Oluremi Tinubu àti àwon tó kùn.
    Ní ìpàdé kejilélógún (22nd) ní ibi ìpàdé àwon sinetò ní agbègbè èkó ….

    English Version after the page break
  • Inú àwon olólùfé 2baba dùn púpò nígbà tí won rí olólùfé won ní Glomega music tour tí ó wáyé ní Victoria Island, ní ìlú èkó. 

    Gbajúgbajà olórin 2baba jé òkan lára àwon tí ó korin ní Glomega tour ní  VI ní ìlú èkó. Ó tún wú àwon ònwòran lórí nígbà tí ó f’akoyo lórí ìtàgé.  Ewo àwòrán bí ó se Ń dá won lárayá n’ísàlè..

    Continue after the page break for the English version

  • Àwon olólùfé Biodun Okeowo wí fun pé kí ó pa àwòrán rè tí ó wo aso tí ó fun ré. 

    Òsèré Biodun Okeowo tí a mò sí Omobutty, ni àwon olólùfé rè ń sòrò sí látàrí àwòrán tí ó pín ní bi tí ó ti wo aso tí ó gbé èyà ara rè jáde…
    Continue after the page break for the English Version
  • Akékòó Odún Keta (300l) Ti Oau Ti Eka Èkó ‘Pharmacy’ Rì Sómi, Tí Ó Sì Kú Sí Odò-ìwè (Swimming Pool) Ní Hòtéèlì. 

    Akékòó odún keta (300l) ti eka èkó pharmacy, Obafemi Awolowo University; pàdánù èmí rè Lánàá léyìn ìgbà tí ó rì sómi nínú odò-ìwè (swimming pool) ní hòtéèlì tí a mò sí Hilton.

    A mò ó sí Fatile Emmanuel. Ìsèlè yí selè nígbà tí Emmanuel lo sí hòtéèlì láti lo lúwèé pèlú àwon Òré rè méji.

    Orísun tí a ti ríi gbó sopé olóògbé náà rì sínú odò-ìwé , látàrí wípé kò tètè rí jákèètì ìdábòbò (life jacket) nígbà tí Ìsèlè náà sè.

     

    Baba Faros, alukoro Pharmaceutical Association of Nigeria Students ni a rí I tí ó so pé; “mo gba ìpè ní nkan bi agogo mérin àbò (4:30pm) Lánàá láti òdò òmòwé kan tí orúko rè ń jé Akinwale (Dr. Akinwale) wípé àwon nílò ìrànlówó mi ní kíákíá ní ilé-ìwòsàn ilé-èkó yìí. OAUTH, nígbà tí mo débè agbà mi ní ìmòràn láti fi ìdí rè múlè wípé ó ti kú tàbí kí á gbé kúrò kí èmí rè tó já tán; a kúrò ní ilé-ìwòsàn ní nkan bí agogo méwàá àbò (10:30pm)ní alé ojó náà “,ó so béè.

     

    Ní inú ìgbà yí. À so fún akoròyìn wípé àwon olóòpá láti Moore ti lo mú òsìsé tí ó wà nípa jákèètì ìdábòbò ní hòtéèlì náà àti àwon akékòó OAU méjì tí won dìjo lo lúwèé ní hòtéèlì pèlú oloogbe.
    Lówólówó yìí, a wà ní Moore ní ilé-isé olóòpá gíga láti gba àwon akékòó méji náà kalè. À ń gbó àwon òrò èyìn díèdíè wípé àwon olóòpá ti kéde ejó náà gégé bi èsùn apanìyàn. Ìgbìmò náà tí bèrè lóòní; Orísun sí…..

    Continue after the page break for English version

  • Ìkan Lára Àwon Ìyá Ń Dá Gbé (Single Mum) Orílè Èdè Nàìjíríà Múra Bíi Okùnrin Láti Se Ayeye Àjòdún Baba (Father’s Day).

    Ò n lo èro ayélujàra (facebook user) Ebere Amalaha tí ó ń jé ìyá ń dá gbé, múra bíi okùnrin láti se ayeye àjòdún baba tí ó wáyé ní ojó kejìdínlógún osù kefà (June 18). Pín àwòrán ara rè bí ó se múra látòkè délè bí okùnrin, “ó sì ko “a kú ayeye àjòdún baba sí gbogbo àwon ìyá ń dá gbé n’íta”…
    Àwòrán míràn léyìn ìjáde

     

    Continue after the page break for the English version.

  • Òrékùnrin Àtijó Vera Sidika Fi Ìhòhò Rè Hàn Látàrí Pé Ó Fi Sílè Bá Olówó Kan Ní Nàìjíríà Lo. 

    Léyìn wíwá ènìyàn pàtàkì ní ìlú Kenya ,Vera Sidika pín àwòrán tí ó fi hàn wípé kò bá ti tún gbàgbé odómokùnrin míràn ní orílè èdè Nàìjíríà tí owó kún àpò rè. òrékùnrin àtijó rè dapadà fún un nípa pínpín àwòrán ìhòhò rè . Èyí se àfihàn. okùnrin kan náà tí Sidika lo gbogbo àkókò rè pèlú, tí ó ma gbe e lo sí ile ìtajà tí ó gbajúmò kan ní Dubai. Tí ó sì wa okò bògìnì pèlú.
     Gégé bí kiss se so, ó pín àwòrán igbáyà tàbí esè omú ènìyàn pàtàkì Kenya tí orí rè sì hàn. Ohun tí ó jé kí á rí àrídájú wípé òun ni. Tàtúù tí ó wà lára Vera ni ó tì wá láti gbàgbó wípé ìhòhò náà ti rè ní…

    Continue after the page break for English version

  • Owó Sìkún Àwon Olóòpá Te Arákùnrin Tí Ó Máa Ń Jí Okò Gbé Ní Yenegoa. 

    Nígbà tí won ti mu fún èsùn kan náà.
    Arákùnrin tí ó wà nínú àwòrán ní ìsàlè yìí tí ó yan isé okò jíjígbé láàyò ni owó sìkún àwon olóòpá bà ní Yenegoa, ní ìjoba ìpínlè Bayelsa fún ìgbà keta.

    Gégé bí ìròyìn se so owó àwon olóòpá ti te afurasí yí rí ní Yenegoa  àti port Harcourt fún èsùn kan náà sùgbón tí ó máa ń bó ní àgo àwon olóòpá.
    Ní àkókò yí, ó tún ti bó bí ó se máa ń bó. Àwon olóòpá sì ti búra láti sìn ín dé bèbè èwòn.,..

    English version
    Continue after the page break.

  • Oko Mi Máa Ń Fowósí Fóòmú Rè Wípé Òun Kò Tí Ní Ìyàwó ,erànmílówó.

     E jò ó Erànmílówó.
    Oko tí ó fémi sílé láti odún mérin séyìn, máa ń fowósí fóòmú rè wípé òun kò tí ní ìyàwó nígbà kúgbà tí ó bá ye kí ó so pé òhun ti láya. Yàtò sí ìyen a kìí sábà ní aáwò kì í sì jowú rárá.
    Njé ó n’ìfé mi ní tòótó?
    Kílódé tí ó ma ń se báyan?
    E jò ó egbà mí ní ìmòràn, kí ni kí n se
    Ìnira yí pò púpò, okàn mi sì ń dà rú gidigidi…

    English Version
    Continue after the page break
  • Ìdí Tí Ó Fà Á Tí Mi Ò Ní Fi Lo Káàdì Ìrántí (Memory Card) Láyémi Mó. 

    Ìdí méji pàtàkì tí mi ò fi lo káàdì ìrántí (SD card) mó.
    SD card tí a mò sí káàdì ìrántí (memory card) tí a tún mò sí káàdì ìrántí ìtá “external memory “,ní tòótó ó jé ohun tí ó wópò tí àwon omo orílè èdè Nàìjíríà ní, sùgbón tí kò papò mó orílè èdè míràn bí àwon se ń lo ohun ayé tuntun tí a mò sí cloud storage (ìpamó àwosánmò )…
    Ó jé wípé… Ó se ni láànú wípé orílè èdè Nàìjíríà jìnà sí lílo irú nkan wònyí, nínú àbájáde yìí máa sàlàyé fún yín ewu tí ó wà nínú lílo káàdì ìrántí (SD card) tí mo sì ní ìgbàgbó wípé okàn yín leè yí láti lo ibi ìpamó míràn bíi ìpamó àwosánmò (cloud storage)
    Ní àkókó n bèrè pèlú ewu ìlo káàdì ìrántí( SD card) …
    1. Ó máa ń fà àìsùn èro ìbánisòrò …
    Njé o ti è ti wòye àbi o ti gbìyànjú láti se àfiwé ìyára tí o bá tan èro ìbánisòrò (phone) re bí? (tí ó túmò sí iye àkókò tí ò ń lò láti tàn  án àti láti pa á?). Tí ó bá sì jé wípé o ti gbìyànjú rè rí, wà sàkíyèsí wípé èro ìbánisòrò re yóò yára tàn láìní káàdì ìrántí (SD card) papàá jùlo àwon tí won ní ìrántí tí ó gbàyè bíi 64,128,256GB…èyí ni ó fa flagship bíi Xiaomi mi6 pèlú èyí tí ó ń bò lónà Essential PH-1 tí won ti gbé sílè láìsí àyè lílo káàdì ìrántí (SD card )…gbogbo atótónu mi ni láti so fún yín wípé káàdì ìrántí (SD card) leè fa àìsùn èro ìbánisòrò (phone) tàbí kí ó dúró sinsin  … E se  sàkíyèsí wípé ó leè jé ohun tí kò ní farahàn nínú àwon èro ìbánisòrò míràn lára àwon tó ní ìlosíwájú àti tó kéyìndé bíi “Snapdragon SOc “tàbí sèsèdé “Mediak Chipsets Series “.
    2. Kòkòrò tí ó máa kolu èro ìbánisòrò (Virus attack).
    Ní tòótó òpó ènìyàn ló mò nípa òtító tí ó korò yìí… Káàdì ìrántí máa ń fa kí Kòkòrò tètè kolu èro ìbánisòrò kò sí síse kòsí  àìse pí paré ni a ó paáré ó sì le fa kí ènìyàn pa ohun tí ó wúlò ré mo bíi Orin, fídíò, àwòrán Abby. Fún àkókò yí mo lérò wípé mo gbìyànjú láti yí okàn yín padà díè, e jò wó mi ò so wípé kí e ma ra káàdì ìrántí (memory card) mó nkan tí mò ń gbìyànjú láti so ni pé… Ìgbà míràn tí e bá fé gba èro. E lo fún èyí tí ìrántí rè pò tí ó sì dára tí e kò fi ní nílò láti ra káàdì ìrántí (SD card) àti àwon ewu tí ó ba wá….

    English version
    Continue after the page break.
  • Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì. 

    Lagos response unit LRU tí a mò sí ìgbìmò ìdálóhùn wá ònà láti gbé okò ńlá tí ó kó yoyo tí ó ta òkìtì látàrí àìmu bírèkì ní òpópónà ojúelégbà, lónà pápá  bóòsì dúró (Stadium bus/stop) kúrò.
    LRU gbé okò náà kúrò lónà…
    Wo òpò àwòrán sì…..

    English version after the page break.