Home / Àṣà Oòduà / Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì. 

Okò Ńlá Tí Ó Kérù Ta Òkìtì Ní Òpópónà Ojúelégbà Ní Ìlú Èkó Látàrí Àìmu Bírèkì. 

Lagos response unit LRU tí a mò sí ìgbìmò ìdálóhùn wá ònà láti gbé okò ńlá tí ó kó yoyo tí ó ta òkìtì látàrí àìmu bírèkì ní òpópónà ojúelégbà, lónà pápá  bóòsì dúró (Stadium bus/stop) kúrò.
LRU gbé okò náà kúrò lónà…
Wo òpò àwòrán sì…..

English version after the page break.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo