Home / Àṣà Oòduà / Òyèkú bìwòrì

Òyèkú bìwòrì

Òyèkú bìwòrì,
Gbóró,gbóró,gìdì ? òyèkú b’ìwòrì?
Ajan gbóró gìdì
Adífáfún lájosìn
Omo ab’oya ríre
Èyí tio bo òrìsà obìnrin là
Èròpo àti tòfà
B’ifá bá..bíni níbè
Oya ni ko maa bo

~Translation ~

Òyèkú bìwòrì
Gbóró gbóró gìdì
Ajan gbóró gìdì
Cast ifá for lájosìn
The one that worship oya with blessings
The one that is destined to worship oya to be successful
People going to ipo, People going to offa
Whenever someone is born with this odù ifá
Must worship òrìsà oya and take her as his or her priority
For him or her to be successful in life.

Àse òrìsà?

About asatiwa

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi

Bàbá Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn

Ẹ jẹ́ kí á jọ kí GBajúmọ̀ Akọrin Jùjú nílẹ̀ yìí, Olóyè Ebenezer Obey Fabiyi kú ayẹyẹ oríkádún wọn ti ọdún kẹtàlélọ́gọ́rin (83) tó kò lónìí. Kí Olódùmarè ó fi àlàáfíà ṣe ẹ̀bùn Ogbó fún Bàbá