Erin jade lenu Ajimobi leyin to feyin Ladoja janle nile ejo


Erin ayo lenu gomina Abiola Ajimobi nigba ti won  pe e lori ago wi pe o ti feyin Adewolu Ladoja janle nile ejo. Gomina Abiola Ajimobi ni ile ejo ti n risi awuyewuye eto idibo gomina ti da lare eleyii to waye lojo Isegun, ana ode yii.

Comments

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *