Home / Àṣà Oòduà / Àwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn.

Àwòrán kí ó tó di onó ìgbéyàwó ti olópàá kan àti olùwòsàn.

Gégé se gégé, onígègè tó pàdé asòpá ni òr olópàá àti olùwòsàn yí jé, bí olópàá bá kojú dogun tí ó sì pa lára, olùwòsàn tí ó jé ìyàwó rè yóò sì ba wò ó sàn .
Àwòrán ti aya tí ó n bò lónà àti oko rè, tí ìyàwó jé olùwòsàn tí oko sì jé olópàá yí mà rewà púpò jú o.

About Awo

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo