Home / Àṣà Oòduà / Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran

Baalu Aare Buhar ti bale niluu Iran

Aare Muhammadu Buhari ti bale ni Tehran to wa ni orileede Iran nibi ti yoo ti maa joko se ipade eleeketa iru e ti egbe awon orileede ti n gbe epo robi jade fun awon orileede agbaye.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Ọrẹ Fálọmọ , Irúnmọlẹ̀ Ìṣègùn Tó Dáńtọ́ Nínú Ìràn Oòduà(Yorùbá) Wọ Káàlẹ̀ Lọ

Ọrẹ Fálọmọ , irúnmọlẹ̀ ìṣègùn tó dáńtọ́ nínú ìràn Oòduà(Yorùbá) wọ káàlẹ̀ lọ Fẹ́mi Akínṣọlá Hùn! Báakú làá dère,èèyàn ò sunwọ̀n láàyè. Ni báyìí, gbogbo ọmọ Oòduà(Yorùbá) ló tí ń sun rárà ọlọ́kan ọ̀ jọ̀kan lẹ́yìn in Dókítà Ọrẹ Fálọmọ tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí oníṣègùn M.K.O Abíọ́lá nígbà ayé rẹ̀.Adarí ẹgbẹ́ Afenifẹre Ayo Adebanjọ nínú ọ̀rọ̀ rẹ̀ sàlàyé pé iṣẹ́ ribiribi ní Ore Fálọmọ ti ṣe nínú ìràn Oòduà(Yorùbá), àti pé ìran Oòduà(Yorùbá) ti sọ ògo ńlá kan nù.Adebanjọ ...