Home / Àṣà Oòduà / Ejò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.

Ejò tí mo pa nínú ilé Adìe mi lóòní.

Ní òní mo gbèrò láti tún ilé àti àyíká Adìe mi se, ni mo pàdé afayàfà yí, mo sá eré bí mo se le sa mo. Nítorí ìgbà àkókò mi rè é tí mà rí ejò ńlá báyìí láàyè, tí kìí bá se lopélopé omokùnrin kan tí mo pàdé, mo rò wípé ejò náà kò bá bó mó mi lówó.
Èyin tí e n’ìfé Ejò n’ílé irú èyà wo ni eléyìí báyìí..

About Awo

2 comments

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?