Home / Àṣà Oòduà / Ogún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi Àgbàlé olófà iná*.

Ogún-l’ógbòn àwon baba ńlá ìran yorùba l’ójé alágbára, lára won ni *Timi Àgbàlé olófà iná*.

Timi Àgbàlé, olóde tí ó sì jé jagunjagun tí Aláàfin rán lo sí ìlú Ede láti dáàbò bo àwon ènìyàn ibè.
Alágbára ènìyàn ni Timi jé , tí a sì mò ó sí *Timi Àgbàlé olófà-iná*,gégé bí ìtàn se so, ó jé okùnrin tí ofà rè má yo Iná.

About Awo

One comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?