Home / Àṣà Oòduà / Gomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò ìdìbò tí won sèsè dì tán ní Anambra.

Gomina Obiano lo kí Ààre Buhari ní Abuja léyìn tí ó gbégbà orókè níbi ètò ìdìbò tí won sèsè dì tán ní Anambra.

Gómìná ti ìpínlè Anambra tuntun, Gómìnà Willie Obiano ní ojó etì (Friday ) ti lo kí Ààre Muhammadu Buhari ní ilé-ìjoba ní ìlú Abuja.
Obiano ti dúpé lówó Buhari nítorí kò se àgàbà-n-gebè níbi ètò ìdìbò tí ó kojá ní Anambra.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?