Home / Àṣà Oòduà / Iyabo Ojo dùn nínú aso tí kò bo ìdodo (crop top) tí ó wò.

Iyabo Ojo dùn nínú aso tí kò bo ìdodo (crop top) tí ó wò.

Ògbó-n-tarìgì òsèré, Iyabo Ojo ti gbe lo sí orí èro ayélujára (Instagram) láti àwòrán ara rè nígbà tí ó ti pé ogójì odún tán , ó sì tún fi hàn wípé dunú.
Òsèré Iyabo Ojo, yó se ayeye ogójì (40) odún ojó ìbí rè ní osù tí ó n bò.
E wo àwòrán n’ísàlè.

About Awo

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?