Home / Àṣà Oòduà / Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara

Ifa Iwure Toni Jade Ninu Odu Ifa Ogundigara

Ekaaro eyin eniyan mi, aojiire bi? Aku aseku odun o emin wa yio se pupo re laye awon alaseku yio bawa se o, ako ni rogun inira o ase.
Ifa iwure toni jade ninu odu ifa Ogundigara
Ifa naa ki bayi wipe:
Jiji ti moji mo rire
Ogbologbo ole lo maa nji to maa nrire
Jiji ti moji mo jifa
Agbalagba ole ni ji ti njifa
Ifa moji loni ki o wa gbemi lede agbele
orunmila moji ki o wa silekun ola gbaragada funmi
Sebi orisa ri gbogbo eranko oko nile
Ko to yan elede laayo, bi ogede bati pon seni ara nde
Ifa jeki ara o demi laye oooooo aseee.
AKOSE RE:……..oooog
Eyin eniyan mi, ara yio de wa loni o, ako ni jare inira eledumare yio dari ìfà ire nla si wa, ogundigara yio lo digara aje nla funwa loni o aaaseee.
ABORU ABOYE OOO.

 

ENGLISH VERSION

continue after the page break

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...