Home / Author Archives: ayangalu (page 25)

Author Archives: ayangalu

Eríwo Yà! Eríwo Yà!! Eríwo Yà!!!

Ṣí Gbogbo Babaláwo àti Oníṣẹ̀ṣe lápapọ̀, Ní òní yìí (ọjọ́ kẹẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n, oṣù kejèe 2019) ni ìgbẹ́jọ́ tó bẹ̀rẹ̀ ní ìtàdògún tó kọjá lọ (Tuesday, 9th of July 2019) parí (tí ìdájọ́ sì wáyé pẹ̀lú) lórí ẹ̀sùn oyún síṣẹ́ fún ọ̀dọ́mọbìnrin tó ...

Read More »

Má Jẹ Àkàrà Ọ̀ràn Sími Lọ́rùn

Aruku madẹgbẹ má jẹ àkàrà ọ̀ràn sími lọ́rùnAruku madẹgbẹ Mo sé ní ìwúre fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní òwúrọ̀ tòní wípé àlejò ọ̀ràn tó ma kóbá èmi àti ẹ̀yin kò ní bá wa ní àlejò ooo

Read More »

Ìwúre Toni

Ikú tó yọ lóòré ńkọ́ Àrùn tó yọ lóòré ńkọ́ Ẹjọ́ tó yọ lóòré ńkọ́ Òfò tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí kọ̀wun, àyà mí kọ̀wunMoti jẹ kọ̀ǹkọ̀ mo ti kọ̀ Owó,aya, ọmọ,gbogbo ire tó yọ lóòré ńkọ́ Orí mí gbàwun, àyà mí gbàwunMoti jẹ ...

Read More »

O lápátí

Kò tirẹ̀ lápátíKò sí ẹni lè gbà pe kí wọ́n dojú ìbọn kọ òwun Mo sé ní ìwúre ní ọ̀sẹ̀ titun ti a wọ inú rẹ̀ yí wípé ògún lákayé kò ní dojú ìjà kọ èmi àti ẹ̀yin tọmọ tọmọ ...

Read More »

E ku Ose Ifa

Aráká-AjagaAràkà-AjagaAdifun Eniyan Ti Mú Iyè Meji Sin ÈdúÈnìyàn Ti O Sin Èdú,Ko Ma Se Iyè MejiAráká-Oku-AjagaAràkà-Oku-Ajaga ??Ase Tedumare?? ?Ifabukky Care?

Read More »

Ìgbín

Àkòrò ní ìgbín fà gungi Ìgbín kò lọ́wọ́ Ìgbín kò lẹ́ṣẹ̀ Àkòrò ní ìgbín fà gungi Mo sé ní ìwúre fún èmi àti ẹ̀yin ní ojúmọ́ tòní wípé Olódùmarè yoo tì wá lẹ́yìn, ìgbìnyànjú wa láti gun òkè ọlà, kò ní já sófo

Read More »

Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..

Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOrí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díOlú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀díNítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ Mo sé ní iwure fún ...

Read More »

Iba Eleiye

Orunmila wi Awo tan.Ifa mi Awo ku mi Bara Agbonmiregun.Ifa ni nibo ni Awo ku si?Mo ni o ku awon Ajagaruwa.Mo ni o ku awon Alsgbede orun ko mero ileke.Mo ni o ku Okoko sii wele. Ifa lo di obiri Mo ni ...

Read More »

Ori mi Apeere

Ka ji ni kutukutuKa mu ohun ipin ko’pind’Ifa fun Olomo-ajiba’re-padeEmi ni mo ji ni kutukutu ti mo f’ohun ipin ko’pinEmi ni mo ba ire pade nigba gbogbo ori mi apeereAteteniranAtetegbeni ju OrishaKo si Orisha ti danni gbe leyin ori eniOri ...

Read More »

Ẹyọ De Ọlọ́bẹ̀ Oko

Ọ̀̀rọ̀ mi gbogbo ka sàì yọ́ ikin nínú gẹ̀ẹ̀rẹ̀gẹ̀ Mo sé ní ìwúre ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ẹ̀sẹ̀ tí a sẹ̀ Ọlọ́run, osó,ajẹ́ àbí ènìyàn bi tiwa ni, tó ń fa ìdíwọ́ kan àbí ìkejì, mo súre fún wa ...

Read More »