Home / Àṣà Oòduà (page 110)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Kabiesi sango o,arabambi arigba ota segun !

Sangiri Lagiri Olagiri kaka figba edun bo Inan Loju Inan lenu Oloju orogbo eleeke obi A tu won ka nibi tiwon gben danan iro….Sango onikoso ooo Happy ose sango day to all onisese here in Nigeria and diaspora?❤️?‍❤️‍?????

Read More »

“OPELE loyo tan to dakun dele

Adifafun perengede Tinseyeye Ojumomo, Ojumotomo wa loni Ojumo aje ni koje fun gbogbo wa Ojumo Ire gbogbo ni ko je fun wa Perengede Iwo ni yeye Ojumomo Ojumo Idun nu ni eni ati gbogbo ojo maje fun gbogbo wa……. ASHEE ...

Read More »

Orewa kilode kilo fa ironu?

Bao ku ise o tan toripe yoruba bo won ni airise koni kapada si orun-alakeji tiko basi oko (farm) ao si ma re idale(travel) ko si eni to la laye yi tiko ni ri nkan wi, amo saa ti oro ...

Read More »

Fi ere si temi Eledumare

Ojulu! ojo nan re bi anan sugbon o ti pe odun kan bayi Eledua modupe, ibi ti ore nan de duro maje ko taku sibe o, fi ere si temi Eledumare, MAJE KIN KAABAMO BO TI WU KORI, orewa toripe ...

Read More »

Orewa Abi Iwonan Ti Gbagbe Ile !

Orewa abi iwonan ti gbagbe ile, toripe eniyan to so ile nu ti so apo ‘ya ko, ajo ko dabi ile lo d’ifa fun agiliti to pada wa tun ile-baba re se, se ki se pe o ti gbagbe orirun ...

Read More »

Oba Erediauwa Ti Waja

Ojulu ooooo! iku ti pa abiri abiri ti rorun alakeji oooo! iku ti pa okan lara awon omo ODUDUWA Oba-Benin, gbogbo eyin ojulowo omoYORUBAatata e ku araferaku eni re OBA-EREDIAUWA ti ile-benin. bo ba de orun ko se orun re. ...

Read More »

Awon osu ni ede Yoruba (12 Months of the Year in Yoruba Language)

E bami kaa si eti awon omo ni ile, January – seere February- Irele March – Erena April – Igbe May – Ebibi June -Okudu July – Agemo August – Ogun September -Owewe October – Owawa November – Beelu December -Ope.

Read More »

Aderupoko lori Eto Gbajumo Osere

Read More »

Bobo B lori Eto Gbajumo Osere

Read More »

YORÙBÁ DÙÚN KÀÁÁÁ

A – Alaafia ni fun o. B – Buburu kan ki yo o subu lu o. D – Dugbedugbe ibanuje ko ni ja le o l’ori. E – Ebi o ni pa o nibi ti odun yi ku si. E ...

Read More »