Home / Àṣà Oòduà (page 153)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Aare Ilu South Africa Ti Sofin Lati Maa Sami Si Oju Ara Awon To Ba Ni Kokoro HIV

Aare ilu South Africa, Jocob Zuma, ti fi owo si abadofin lati maa sami si egbe kan oju ara awon ti won ba ni kokoro HIV lara. Won ni nipa sise eleyii, yoo mu adinku ba awon eniyan ti won ...

Read More »

Yeepa! Ki le yii?

O Dabi Eni Wi Pe Inu Osupa Ni Maanu Yii Ti Wa

Read More »

E Wa Wo Ohun Ti Omokekere Yii Da Lara: Eleyii Koja Afenu So

Lara awon iroyin wa to ti jade tele, awon iroyin lori ate Olayemi Oniroyin, mo se lalaye wi pe Edua Oke ko da ile Adulawo gege bi ibugbe awon otosi ati alaini; awon olori wa lo so ilu wa di ...

Read More »

Omo Naijeria Setan Lati Dije Fun Ipo Aare Orileede Spain

Ko to di wi pe ma kan lu agbami oselu ti n gbona felifeli bayii ni ilu Spain, nibi ti Arabirin Helen Mukoro to je omo ipinle Delta lati orileede Naijeria ti setan lati dije fun ipo aare orileede Spain, ...

Read More »

E Wo Ohun Ti Awon Omo Ile Igbimo Asofin Se Lodun 1962

Awon omo ile igbimo asofin Nigeria ti n foganna lojo to ti pe, ohun ti won se ni yii lodun 1962 nigba rogbodiyan Western Region.   Orisun

Read More »

Yomi Fash – Lanso N Jaye Oloba Niluu Côte d’Ivoire

YOMI FASH – LANSO Orisun +Wale Ojo-Lanre

Read More »

Oniroyin Meji Ti Wa Ni Kirikiri Bayii: Ise Iroyin Won Lo Ko Ba Won

Alase banki Fidelity ti Nigeria, Ogbeni Nnamdi Okonkwo ni Oniroyin Seun Oloketuyi gbe saye lori ikanni re, www.naijahottestgist.com wi pe oga banki naa feran ko maa se “yodiyodi” fun awon osisebirin banki re. O ni yato si awon osisebirin re, ...

Read More »

Iresi Gomina Ayodele Fayose Tun Pada Wo Ipinle Ekiti

Ikere Ektiti ni won ti pin. Atomode atagba, arugbo naa gba ninu iresi Fayose. Ohun ti awon eniyan so nipa re wa nibi:

Read More »

Oko Ajagbe Eleru Leyin Jabo Lati Ori Afara Ojuelegba: Emi Awon Eniyan Ba Lo

Oko ajagbe eleru leyin kan jabo lati ori afara to wa ni Ojuelegba niluu Eko losan-an oni. Eniyan meji to wa ninu oko ti ajagbe naa jabo le lori fi ile aye sile loju-ese ti isele naa waye nigba ti ...

Read More »

Oriki Ibeji : Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún

Ẹ̀jìrẹ́ ará ìṣokún. Ẹdúnjobí Ọmọ ẹdun tíí ṣeré orí igi Ọ́-bẹ́-kẹ́ṣé-bẹ́-kàṣà, Ó fẹsẹ̀ méjèèjì bẹ sílé alákìísa; Ó salákìísà donígba aṣọ. Gbajúmọ̀ ọmọ tíí gbàkúnlẹ̀ ìyá, Tíí gbàdọ̀bálẹ̀ lọ́wọ́ baba tó bí í lọ́mọ. Wínrinwínrin lójú orogún Ejìwọ̀rọ̀ lojú ìyá ...

Read More »