Home / Àṣà Oòduà (page 151)

Àṣà Oòduà

Àṣà Oòduà, Asa Ibile Oòduà. Oòduà (Yoruba) je okan ninu awon eya ti o laju ju lode aye yi. Lati igba ti alaye ti daye ni won ti ni eto ati ilana to kun nipa ohun gbogbo ti won nse ni igbesi ayee won.

Diezani Alison-Madueke Wo gau! Madaamu Naa Setan Ti O Foju Bale Ejo

Owo awon olopaa ilu London ti te Diezani Alison-Madueke to je minisita fun epo robi nigbakan labe isejoba Goodluck Jonathan. Alison-Madueke ati awon merin kan ni owo te laaro ojo Eti to koja yii pelu esun Jegudujera, riba ati sise ...

Read More »

Ara Orisiirisii Nibi Igbeyawo Aye Ode Oni

Iru sitayi wo leyii?

Read More »

Ohun to mu Odun Ominira eyi yato si ti igba ti Goodluck Jonathan wa lori oye

Ara opo awon omo Naijiria tun ya gaga si orile ede won lojo Alamisi to koja, nigba ti a se ayeye ominira odun karunlelaadota. Kaakiri awon ipinle, opo eniyan lo ki akegbe won ku oriire, ti won si n soro ...

Read More »

Awon Oruko Minisita Buhari Lati Enu Awon Omo Naijeria Niyii

Awon Minisita Buhari: Niwon igba ti awon ara ilu si n reti oruko awon eniyan ti Aare Buhari fe fi je minisita, awon oruko wonyii ni awon ara ilu ni oseese ko jeyo ninu awon oruko minisita ti Buhari ko ...

Read More »

Ajimobi ati Amosun Da Ara Ilu: Won Ni Ko Si Eko Ofe Mo

Lati inu iwe Iroyin Owuro to jade lose to koja ni iroyin naa ti jade wi pe Ajimobi ati Amosun ti pada ninu ileri eto eko ofe ti won se ileri re fun awon ara ilu. Won ni ki olomu ...

Read More »

Se N’Ibadan Tia Nile Oluyole?

Ibadan tia! Se n’Ibadan tia? Ibo lawa o mo lOluyole Ibadan? MAPO d’AYẸYẸ Gbogbo ODÍNJÓ tia ni, ELEKURỌ, ALEKUSỌ, Ibo gan-an lawa o mo n’Ibadan? BẸRẸ titi to fi de ÒÓPÓ Yoosa, Ibi to ku taa mo ni ke e ...

Read More »

Tai Solarin Dilu Nla

Tai Solarin dilu nla Tai Solarin ile ẹkọ nla to dilu nla. Ibi ọgbọn gbe pamọ si. Arọni imọ ti n ja ni laya bi oke. Gbékanlùkan isẹ ọpọlọ to fakíki. Kinihun o jẹran ikaṣi. To ba jọ bi irọ, ...

Read More »

Olopaa Ko Le Mu…

Okan lara awon aworan to jade lati ipinle Bauchi sori ayelukara lojo odun ileya to koja ni yii.  Lotito, olopaa ko le mu won. Nitori olopaa kan wo won lotito ko si le da won duro. Sebi odun lo de.

Read More »

Enu Kofi Omo Ghana Pada Re Ba a Lese

Eyin eniyan mi, ohun kan se pataki ti mo fe ko da wa loju; ti mo si fe ki oye re ye wa gidi.  Igbe aye eniyan wa ninu oro siso tabi ohun ti a fenu se ijewo re. Iru ...

Read More »

Ogo Omu-Aran Ni Ipinle Kwara Pe Eni Odun Mokanlelogota (61)

Oni, 27-09-2015, ni Bisoobu Dafiidi Olaniyi Oyedepo pe eni odun mokanlelogota (61). Omo bibi Omu Aran ni ipinle Kwara ni i se, oun kan naa ni oluso aguntan agba fun ijo Living Faith Ministry to kari aye pata. Onkowe ni, olukoni oro ...

Read More »