Home / Àṣà Oòduà / Bukola Saraki Wo Gau: Won Pada ‘geti’ Maanu Naa

Bukola Saraki Wo Gau: Won Pada ‘geti’ Maanu Naa


Leyin awon esun bi metala ati esun iro funfun ti Bukola Saraki pa nipa jijewo dukia to ni. Ile ise ijoba apapo, eka ti awon onidajo ti pase ki ile ise olopaa ile yii, labe akoso ogbeni Solomon Arase lo gbe Saraki latari wi pe o ko lati yoju si ile ejo lori awon esun ti won fi kan-an.

Won ni maanu naa jo ra re lo ju pupo ju. Se tori wi pe o je aare ile igbimo asofin agba lo je ko maa se galigali, ko maa se bi eni wi pe oun ti ga jofin lo?  Bi o tile je wi pe Sariki ti pada toro aforijin, sibesibe onidaju Danladi Umar ni a fi ti awon olopaa ba gbe e, ki won di bi eru okirika, ki won si so jua sile niwaju oun.
Orisun: Olayemioniroyin.com

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Ìdíle Saraki àti ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara dájọ́ ìpàdé

Lẹ́yìn tí Ìjọba Ìpínlẹ̀ Kwara ti tẹ̀lé òfin tí wọ́n wo ohun ìní ìdílé Saraki èyí tí wọ́n ń pé ibẹ̀ ni Ilé Arúgbó ní ìlú Ilorin, ìpínlẹ̀ Kwara, gbogbo àwọn tọ́rọ̀ kan nínú rẹ̀ ti wá gbà láti yanjú aáwọ̀ láì ti ọwọ́ Ilé ẹjọ́ bọ̀ ọ́ mọ́.