Home / Àṣà Oòduà / Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72)

Olatunbosun Oladapo Patan Ayo Leni Odun Mejilelaadorin (72)


Ojo ibi baba tun ti wole de. Ki n maa paro, owo mi n gbon, mi o si mo ohun ti maa ko gan-an lati fi ki baba rere. Mi o tile mo iru agbekale asanyan oro ti mi o ba lo to le se aponle baba bi mo se fe gan-an lokan mi.  Baba je eni to nifee, ti won si ko opolopo eniyan mora. Bi ohunkohun ba ru ni loju, ti e ba pe baba, suuru ati ayo ni baba fi n dahun.

Adura mi ni wi pe ke e pe laye, ninu alaafia, ifokanbale, ogbon ati ilera to peye. Tope Falaanu ni ki n ki yin, Adewale Dada Thegood naa si fise ran mi. Won ni igba odun, odun kan ni. Ase

Olatunbosun Oladapo ti bere si ni se afihan awon aworan won aye atijo lati fi dupe lowo Oluwa fun irin-ajo odun mejilelaadorin ti won ti n ba bo lori erupe ile. Awon aworan naa ni yii nisale pelu awon akole baba:

 

Orisun: olayemioniroyin

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Àrùn burúkú fé̩ tú Queens college

Arun iba buruku kan n da yanpon- yanrin sile bayii ni ile-ise awon obinrin (Queens college) to wa ni ilu Eko.Ironu ti dori awon agba kodo ni ipinle Eko bayii paapaa julo fun gbogbo awon to lomo nibe. Ile-iwe yii loruko to dara lati odun to ti pe. Ibe ni opo awon omo eniyan pataki lawujo n fi omo won si ki o to di pe awon ile-iwe aladaani tu jade ni nnkan bii ogoji odun seyin. Ko tii pe ...