Home / Àṣà Oòduà / Ta Ni Elújoba?

Ta Ni Elújoba?

Elújoba ni gíwa tí ó kúrò
Lóríi oyè gégé bíi alásé oau
Láìpé yìí
Tí gbogbo ènìyàn sì n kan sárá sí òjògbòn náà
kìí kúkú se pé wón n déédé kan sáárá sí Baba
Ìwà rere àti òótó inú tí Baba
fi n sisé ló jé kí ójògbón ó gbayì lárà òtò
Omo Elújoba kò kò ju odún kan lo, kí ó tó san gbogbo 
owó àwon òsìsé tó n fa wàhálà kí ó tó gba èkù idà
ìyàlénu ni pé àwon tó ó tukò ogbà fémi télè fún bíi odún márùn-un séyìn won kò rí àseyorí kan tóka sí àmo ní géré tí òjògbón dé ìròrùn dé bá terútomo logba èyí tó kàmàmà ni pé
títí elújoba fi kúrò nípò àwon òsìsé kò dasé sílè rárá
ìtàn tí kò se gbàgbé nìyí nínú ogbà
Sé ó wá ye ká gbó pé irú eni rere béè ni àwon (efcc) wá lo fi sí àtìmó hmmmmm
ó rúmi lójú
oro yòrùbá sèsè wá yémi pe
aráyé ò fé òótó
èsùn tí wón fi kan Baba ni pé ó sanwó àwon òsìsé pèlú owó tí kìí se ti òsìsé
èyí ló mú kí àwon òsìsé ó bínú tí àwon akékòó náà sì gbarata pé kàkà kéku má je sèsé a ó fi sàwàdànu ni
Èyí ló fàá tí èèrò fi yabo ilé ejó tí wón sì n sòrò pèlú èdùn okán àti òpòlopò àkólé lówó tí ó so pé
E fi Elújoba sílè eni tó ye kí e mú, e ò mú u…..
hmmmmmmm
Àmó èmi mò pé fínni ni adìe n toko ìmó bò ni òrò náà yóò jé fun Elújoba
Ìdí tí mo fi be gègé lówè ni pé
ibò gan n lòrò Nigeria n lo?

*ODUNEWI PRODUCTION ..*

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo