Home / Àṣà Oòduà / Aku ojumo lokun !

Aku ojumo lokun !

Lobinrin wa se dada laji bii.. Adupe lowo OLODUMARE too mu emi ati iwo losii ipo oku lati ano too tun jiwa pada saiye, si aye rere nitori gbogbo eni bati sun ti oku ope ni fun ODUMARE.. Moo wa nfi asikoyi se ni iwure wipe bi aba se jade loo lowuro toni pelu ASE oLODUMARE a o nijade lu iku lowo, a o nigba ipe apuru beeni a o ni gburo okere banu je… Owo a maje fun ori kankan wa… IFA kan so ninu odu mimo e nigba ti OLODUMARE nba ASIWAJUWA ORUNMILA…
Oni… Iwaju iwaju ni opa ebiti un ree si ADIFA FUN OJU NIJO TIN RE ILU OWO (won ni o karan nile EBO ni kose– OJU RUBO)….
Nje eje ki o lowo o lo owo, owo koko lafin wo igi, owo orisa labuu fun afin, lowo lowo lakun owun abeemi. Owo eje ki olo wo o lo. Gbo owun buburu yio ma dowo fun emi ati iwo…. ASE… EJIRE OOoOOoOO

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...