Home / Àṣà Oòduà / Ojuitere !

Ojuitere !

ojuitere, iba re’oo baba IFAYEMI ELEBUBON, iba
re’oo baba PETER IFATOMILOLA, iba re’oo baba,
ADEBAYO IFALETI, baba wa AWODIRAN AGBOLA
baba ADEGBOYEGA OMO ODO AGBA, awon agba
onifa ti won gbo n’ti
ifa n’so, sebi Yoruba bo won ni, KOSI ENI TO GBO
ILU TO ENI TO MU OPA-ILU DANI, awon agba onifa
je koye wa wipe ojise Eledumare ni ifa se, asa
(culture) yato si esin(religion) e ma fi asa we esin,
toripe, KI OLORI TO DI ORI LATI N’DI ORI EWA FUN
AKUKO, atipe KI AGBADO TO D’AYE N’KANKAN NI
ADIYE N’JE. iba l’owo gbogbo onifa aye, e bami jise
mi fun ifa, IFA-OLOKUN ASORO D’AYO ELERIPIN
A’TUN ORI ENI TI O SUNWON SE. moki ifa mosi tun
ki gbogbo onifa patapata, toripe, MO GBO
WOBOWOBO IFA KIN TO WOLE, MO DE EYINKULE
TAN MO TUN MO IYE ODU TO WU. òjú-ìtèrè
ojulowo omoYORUBA atata.

About ayangalu

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...