Home / Àṣà Oòduà / Taiwo Osuolale (Ibeji Oran) naa ti ku o

Taiwo Osuolale (Ibeji Oran) naa ti ku o

Lose to koja ni iroyin nipa iku Taiwo Ibeji Oran fe si wa leti, e le ka iroyin naa ninu linki isale yii.
www.olayemioniroyin.com/2015/10/ki-lo-sele-si-taiwo-leyin-iku-kehinde.html
Iroyin naa ti fidi mule bayii. A si tun gbo wi pe won ti sin Taiwo sinu ile re to wa ni ipinle Osun. Isele yii lo waye leyin odun kan ti Kehinde re dagbere faye.  Taiwo fi omo kan sile saye lo eleyii ti aya re igba kan, Folake bi fun un.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Bí Ẹ Bá Rí Ilá L'ọ́jà Kí Ẹ Ma Rà Fún Mi

Bí Ẹ Bá Rí Ilá L’ọ́jà Kí Ẹ Ma Rà Fún Mi

Mo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹBí ẹ bá rí ikàn l’ọ́jà kí ẹ ma rà fún miMo ní èmi ò fẹ́Mo ní èmi ò jẹAtẹ̀gbẹ̀ tí o bá délé Olódùmarè kí o ra ọmọ wẹrẹ wá fún miA dífá fún Àbẹ̀kẹ́ tí ń se eléwùrà l’ọ́jà tí n se elépo ní imọdẹ àgàn òde àpàẸkún ọmọ lo n sunÒun le bímo lópòlopò ni ndafa síẸbọ lawo ni kóseKò sí ohun tó wuyì ju ọmọ lọỌmọ làdèlé ẹniKò ...