Home / Àṣà Oòduà / Salawa Abeni korin pelu omo re, BIG SHEFF

Salawa Abeni korin pelu omo re, BIG SHEFF


BIG SHEFF ni yii, omo SALAWA ABENI.
Sheriff Ilori je okan lara omo ti Queen Salawa Abeni bi fun Oba Fuji Alatika, Alhaji Rasaki Kolawole Ilori, eni ti gbogbo eniyan mo si Gen. Kollington Ayinla.

Big Sheff je olorin Hip pop, eleyii ti irisi re fe jo ti Rick Ross ti ilu Amerika. Ijora Big Sheff lo mu awon kan maa pe ni Rick
Ross ile Naijiria.

Oun ati iya re jo korin nibi ayeye olodoodun ti won se niranti Fela Anikulapo Kuti ti won pe ni Felabration.

Orisun

About oodua

One comment

  1. OMG! What is this? This man should pls visit d gim 4d sake of his heart health

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

“Ta Ní Ó Wà Kí Ayé Tó Wà? Ìtàn Àkọ́kọ́ Ìṣẹ̀dá Gẹ́gẹ́ Bí Ifá Ṣe Sọ Ó.”

Kò sí ohun ẹlẹ́mìí kankan láyé awo ilé Ayé ni ọ̀run àkọ́kọ́, ohun tí ó so kàrà tí kò sọ̀kalẹ̀, awo òde Ọ̀run ni ó ń pè é, gbogbo rẹ̀ jẹ́ òfìfo lásán, òfo pónbele, láìní ìpìlẹ̀, láìní ẹ̀dá kankan, Awo àárín gbùn-gbùn òde ni ó wí i, A dífá fún Ayé àti fún Ọ̀run, nínú ìkarawun ìgbín méjì tí ó ṣófo, kò sí ẹyẹ, kò sí ẹ̀mí tí ń gbé inú wọn, ìpìlẹ̀ kò tí ì sí, afẹ́fẹ́ kò ...