Home / Àṣà Oòduà / Ajimobi ati Amosun Da Ara Ilu: Won Ni Ko Si Eko Ofe Mo

Ajimobi ati Amosun Da Ara Ilu: Won Ni Ko Si Eko Ofe Mo


Lati inu iwe Iroyin Owuro to jade lose to koja ni iroyin naa ti jade wi pe Ajimobi ati Amosun ti pada ninu ileri eto eko ofe ti won se ileri re fun awon ara ilu. Won ni ki olomu da omu iya re gbe; won ni ki awon obi maa san owo idanwo asejade (WAEC) awon omo won funra won.

Ki ni ero awon eniyan nipa igbese tuntun yii? E le ka awon ero ara ilu ninu linki isale yii.

Orisun

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Kini eleyi ni ede Yoruba tabi ede Oduduwa

Ìbéèrè tóni

Ìbéèrè lórí kíní “Solar System”ni Èdè Yorùbá?