Home / Àṣà Oòduà / Ànto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè

Ànto Lecky wo Ejò rògbòdò yíká orún rè

Ará ilé Bbnaija télè tí a mò so Anto ti gbé àrà òtun yo fún àwon olólùfé rè, nígbà tí ó lo sí àgbàlà ejò rògbòdò ní orílè èdè Republic of Benin.

Ó ko síbè wípé:
” Ní àgbàlá ejò nlá nígbà tí mo rin ìrìn àjò lo sí Quidah, orílè èdè Benin Republic

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.