Home / Àṣà Oòduà / Davido, Gbajúgbajà olórin tí ó tún jé omo ebí Adeleke wo agbádá tí àwon egbé oní Àsìá se tí won sì ko orúko egbé won si.

Davido, Gbajúgbajà olórin tí ó tún jé omo ebí Adeleke wo agbádá tí àwon egbé oní Àsìá se tí won sì ko orúko egbé won si.

Olórin, tí ó tún jé òtòkùlú ti n se isé takuntakun láti ri dájú wípé, sínétò Ademola Adeleke di Gómìnà ìpínlè Òsun ní ibi ìdìbò tí ó n bò ní ojó àbáméta yí.

Ó tí è ti n sisé takuntakun láti polongo fún egbé PDP fún ègbón rè tí ó fé lo fún ipò gómìnà ní ojó àbámétà .
Èyí ni àwòrán ibi tí ó ti wo aso PDP fún Òsogbo ní ibi tí ó ti n polongo.

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.