Home / Àṣà Oòduà / E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?

E fun mi ni owe to ni Ile(house) ninu ?

Edakun gbogbo ile, e fun mi ni owe to ni ile(house) ninu.

E seun.

About ayangalu

6 comments

  1. Ile la n wo, ka to somo loruko

  2. Ile Oba to Jo, ewa lo bu si

  3. Ile oloke meje kose fii bomode sere…..

  4. Ile ni apoti n joko de idi

  5. Ile la tin kesho ro dé

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.