Home / Àṣà Oòduà / Favour Iwueze ti Destined kids ti setán láti se ìyàwó.

Favour Iwueze ti Destined kids ti setán láti se ìyàwó.

Omo kékeré àná náà ti dàgbà, àdúrà wa ni wípé kí olórun má pa omo fún olómo. Favour Iwueze ìkan lára àwon omo kékeré ìgbàyan ti setán láti se ìgbéyàwó, kí ire ayò náà kárí.

About Awo

One comment

  1. Oh! What a good news!! I wish her a happy married life, fruitful marriage & a peaceful home. Pls tell… https://t.co/EtG8S6htDP

Leave a Reply to okbabs Cancel reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.