Home / Àṣà Oòduà / Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi

Fayose kò mo̩ bò̩ò̩lì àti àgbàdo je̩ tó mi,àmó̩… – Fayemi

Gomina ipinle Ekiti, Dr Kayode Fayemi lo n salaye yii nibi eto ori telifison Kan ti arabinrin Morayo Afolabi n dari re.

Leyin ti gomina dahun orisiirisii ibeere ni arabinrin naa wa tun beere asepo to wa laarin oun ati gomina ana ni ipinle naa, Alagba Ayodele Fayose.
Fayemi ni asepo to dan moran wa laarin awon. O ni koda awon pade ni ode kan ti Ojogbon Afe Babalola ti lo gba ebun laipe.

O ni awon si soro daadaa, koda awon tun da apara.
Fayemi ni ko si ija tabi ita laarin awon. Ibe naa ni gomina Fayemi tun ti dahun ibeere iyato to wa laarin awon ti kii se eebu. O ni Olorun lo da onikaluku ni otooto.

O ni gbogbo nnkan daadaa ti Fayose n je ni oun naa le je, o ni koda Fayose gan-an mo pe ko lemii oun nibi agbado ati booli jije. O ni amo oun ko le maa jee laarin oja bii tire.

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.