Home / Àṣà Oòduà / Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..

Iwure Toni: Orí Ma Jẹ Kí Ire Tí Moní Kó Pẹ̀dí ..

Ifá ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀dí
Orí ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀dí
Olú ọ̀run ma jẹ kí ire tí moní kó pẹ̀dí
Nítorí ata wẹẹrẹ kín pẹ̀ dí nínú ọbẹ̀ ata wẹẹrẹ

Mo sé ní iwure fún orí kọ̀ọ̀kan wa ní ojúmọ́ tòní wípé gbogbo ire tí kálukú wa bá kójọ kò ní pẹ̀dí mọ́ wa lọ́wọ́ o láṣẹ Olódùmarè. Àsẹ

About ayangalu

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.