Home / Àṣà Oòduà / Linda Ikeji padà so orúko baba omo rè, ó wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun àti oko tí n bò lónà.

Linda Ikeji padà so orúko baba omo rè, ó wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun àti oko tí n bò lónà.

Elétí Ofe, Linda Ikeji ti padà so baba omo rè, ó sì ti so wípé Sholaye Jeremi ni baba omo òun .

Ó tún so wípé orúko omo òun ni Jayce Jeremi , ó ko síbè wípé…
” mò n re’lé pèlú omo oba mi. Ìbèrè odún rere nínú ayé mi! Orúko rè a máa jé Jayce, Jayce Jeremi si ni yó ma jé.
N wó pín àwòrán láìpé”

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.