Home / Àṣà Oòduà / Odún pé, odún jo, àmòdún wa èsín pé.

Odún pé, odún jo, àmòdún wa èsín pé.


Ikú bàbá yèyé, Aláse èkejì Òrìsà, baba wa Aláàfin ti ilè Òyò, Oba Lamidi Adeyemi 111 se ayeye ojó ìbí rè ní òní tí won pé ogórin odún (80).
Àrà méèrírí ni kábíèsí, Ikú bàbá yèyé nítorí baba ni wón lójó gbogbo. Won kò sí jé kí Àsà Yorùbá parun rárá, won n gbé Àsà láruge nígba gbogbo.
Òmo oòdua kí Aláàfin kú àjòdún ojó ìbí won, baba kí e pé ooo.

About Awo

x

Check Also

Orun Ire Ooooo

ERIN WOOOOOOO. Iku da Oro iku shei’ika, Iku mu eni rere lo.