Home / Ajeji Gisiti / Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko

Omiyale-agbara ya soobu ti se ijamba niluu Oba Biritiko

Aimoye dukia lo ti sofo bayii latari iji nla pelu agbara ojo ti n wo odindi moto sare ni ilu England bayii. Isele buruku yii lo waye latari ojo alagbara kan to si lule to si bere si ni se ijamba lorisiirisii. Gege bi alaye to te Olayemi Oniroyin lowo, apa ariwa ilu UK ni ijamba naa ti wopo julo nibi ti won ti ro gbogbo olugbe agbegbe naa lati sa asala fun emi won bayii.

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*

x

Check Also

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

Òfún kò rẹ́tẹ̀ be yín

A kì í wípé kí ọmọ olówó kó má se yín gan-an gan-anBó bá ṣe yín gan-an gan-an a o ni fètè ìwọ̀fà boA dífá fún Ọ̀rúnmìlà wọ́n ní kí baba kó fi ẹbọ araa rẹ̀ sílẹ̀Wọ́n ní Ẹbọ ayé gbogbo ni kí baba o seỌ̀rúnmìlà ní kí ọmọ Osó kó mà kú oBaba ní k’ọ́mọ Àjẹ́ kó yèNítorí wípé ẹbọ ayé gbogbo ni mo nseIre oo