Home / Àṣà Oòduà / Se atunbotan aye ti de ba Madueke ni?

Se atunbotan aye ti de ba Madueke ni?

Foto tuntun Diezani Allison-Madueke ni yii, minisita fun epo robi nigba kan ri, eni ti won fesun jegudujera kan niluu London. Won ni ara madaamu naa ko ya rara. Joojumo si ni ipo ilera re n buru sii. Arabirin naa niidi adura bayii, ki Olorun alaanu ba wa da alaafia pada si lara. Ase !
Olayemioniroyin.com

About oodua

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

*